Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 33:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó súre fún ẹ̀yà Lefi pé:“OLUWA, fún Lefi, ẹni tíí ṣe olódodo, ní Tumimu ati Urimu rẹ;Lefi, tí o dánwò ní Masa,tí o sì bá jà níbi odò tí ó wà ní Meriba;

Ka pipe ipin Diutaronomi 33

Wo Diutaronomi 33:8 ni o tọ