Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 33:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó súre fún ẹ̀yà Juda pé:“OLUWA, gbọ́ igbe ẹ̀yà Juda,nígbà tí wọ́n bá pè fún ìrànwọ́,sì kó wọn pada sọ́dọ̀ àwọn eniyan wọn.Fi ọwọ́ ara rẹ jà fún wọn,sì ràn wọ́n lọ́wọ́ láti borí àwọn ọ̀tá wọn.”

Ka pipe ipin Diutaronomi 33

Wo Diutaronomi 33:7 ni o tọ