Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 33:11 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, bukun àwọn ohun ìní wọn,sì jẹ́ kí iṣẹ́ ọwọ́ wọn jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà lójú rẹ,Fọ́ egungun itan àwọn ọ̀tá wọn,tẹ̀ wọ́n ní àtẹ̀rẹ́,kí àwọn tí wọ́n bá kórìíra wọn má sì lè gbérí mọ́.”

Ka pipe ipin Diutaronomi 33

Wo Diutaronomi 33:11 ni o tọ