Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 31:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Òní ni mo di ẹni ọgọfa ọdún (120), kò ní ṣeéṣe fún mi mọ́, láti máa fò síhìn-ín sọ́hùn-ún. OLUWA ti wí fún mi pé, n kò ní gun òkè odò Jọdani yìí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 31

Wo Diutaronomi 31:2 ni o tọ