Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 31:3 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun yín tìkalára rẹ̀ ni yóo ṣiwaju yín lọ, yóo ba yín pa gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè náà run, tí ẹ ó fi lè gba ilẹ̀ wọn. Joṣua ni yóo sì jẹ́ olórí, tí yóo máa ṣiwaju yín lọ, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti wí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 31

Wo Diutaronomi 31:3 ni o tọ