Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 28:64 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo fọ́n yín káàkiri àwọn orílẹ̀-èdè ayé, ẹ óo sì máa bọ oríṣìíríṣìí oriṣa káàkiri, ati èyí tí wọ́n fi igi gbẹ́, ati èyí tí wọn fi òkúta ṣe, tí ẹ̀yin ati àwọn baba yín kò mọ̀ rí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:64 ni o tọ