Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 28:63 BIBELI MIMỌ (BM)

Gẹ́gẹ́ bí ó ti jẹ́ dídùn inú OLUWA láti ṣe yín ní rere ati láti sọ yín di pupọ, bákan náà ni yóo jẹ́ dídùn inú rẹ̀ láti ba yín kanlẹ̀ kí ó sì pa yín run. OLUWA yóo le yín kúrò lórí ilẹ̀ tí ẹ̀ ń wọ̀ lọ láti gbà.

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:63 ni o tọ