Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 28:65 BIBELI MIMỌ (BM)

Ara kò ní rọ̀ yín rárá láàrin àwọn orílẹ̀-èdè wọnyi, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò ní rí ìdí jókòó. OLUWA yóo mú jìnnìjìnnì ati ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn ba yín, yóo sì mú kí ojú yín di bàìbàì.

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:65 ni o tọ