Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 28:12 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo fún ọ ní ọpọlọpọ òjò ní àkókò rẹ̀ láti inú ilé ìṣúra rẹ̀ lójú ọ̀run, yóo sì bukun iṣẹ́ ọwọ́ rẹ. Ìwọ ni o óo máa yá ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè ní nǹkan, o kò sì ní tọrọ lọ́wọ́ wọn.

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:12 ni o tọ