Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 28:13 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo fi ọ́ ṣe orí, o kò ní di ìrù; òkè ni o óo máa lọ, o kò ní di ẹni ilẹ̀; bí o bá pa òfin OLUWA Ọlọrun rẹ, tí mo pa láṣẹ fún ọ lónìí mọ́, tí o mú gbogbo wọn ṣẹ lẹ́sẹẹsẹ,

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:13 ni o tọ