Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 28:11 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA óo fún ọ ní ọpọlọpọ ọmọ, ati ọpọlọpọ ẹran ọ̀sìn. Àwọn igi eléso rẹ yóo máa so jìnwìnnì ní ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun rẹ búra fún àwọn baba rẹ, pé òun yóo fún ọ.

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:11 ni o tọ