Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 24:6 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ẹnikẹ́ni bá yá eniyan ní nǹkankan, kò gbọdọ̀ gba ọlọ tabi ọmọ ọlọ tí ẹni náà fi ń lọ ọkà gẹ́gẹ́ bíi ìdógò, nítorí pé bí ó bá gba èyíkéyìí ninu mejeeji, bí ìgbà tí ó gba ẹ̀mí eniyan ni.

Ka pipe ipin Diutaronomi 24

Wo Diutaronomi 24:6 ni o tọ