Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 24:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ọkunrin kan bá ṣẹ̀ṣẹ̀ gbeyawo, kò gbọdọ̀ jáde lọ sí ojú ogun tabi kí á fún un ní iṣẹ́ ìlú ṣe, ó gbọdọ̀ wà ní òmìnira ninu ilé rẹ̀ fún ọdún kan gbáko, kí ó máa faramọ́ iyawo rẹ̀ tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́.

Ka pipe ipin Diutaronomi 24

Wo Diutaronomi 24:5 ni o tọ