Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 24:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ẹnìkan bá jí ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Israẹli ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ gbé, tí ó sì ń lò ó gẹ́gẹ́ bí ẹrú, tabi tí ó tà á, pípa ni ẹ gbọdọ̀ pa olúwarẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni ẹ óo ṣe mú ohun burúkú yìí kúrò láàrin yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 24

Wo Diutaronomi 24:7 ni o tọ