Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 14:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeroboamu jọba fún ọdún mejilelogun. Lẹ́yìn náà, ó kú, wọ́n sì sin ín. Nadabu, ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 14

Wo Àwọn Ọba Kinni 14:20 ni o tọ