Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 14:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn nǹkan yòókù tí Jeroboamu ọba ṣe: àwọn ogun tí ó jà, ati bí ó ti ṣe ṣe ìjọba rẹ̀, gbogbo rẹ̀ wà ninu ìwé àkọsílẹ̀ Ìtàn Àwọn Ọba Israẹli.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 14

Wo Àwọn Ọba Kinni 14:19 ni o tọ