Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 21:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Manase ọba ti ṣe àwọn ohun ìríra wọnyi, wọ́n burú ju èyí tí àwọn ará Kenaani ṣe lọ. Ó sì mú kí Juda dẹ́ṣẹ̀ nípa pé wọ́n ń bọ àwọn ère rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 21

Wo Àwọn Ọba Keji 21:11 ni o tọ