Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 21:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA Ọlọrun Israẹli ní òun óo mú ìparun wá sórí Jerusalẹmu ati Juda, tóbẹ́ẹ̀ tí yóo jẹ́ ìyàlẹ́nu gidigidi fún ẹnikẹ́ni tí ó bá gbọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 21

Wo Àwọn Ọba Keji 21:12 ni o tọ