Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 2:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliṣa bá dá wọn lóhùn pé, “Ẹ bu iyọ̀ sinu abọ́ tuntun, kí ẹ sì gbé e wá fún mi.” Wọ́n bá ṣe bí ó ti wí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 2

Wo Àwọn Ọba Keji 2:20 ni o tọ