Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 2:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin ìlú náà wá sọ́dọ̀ Eliṣa, wọ́n sọ fún un pé, “Ìlú yìí dára gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin náà ti mọ̀, ṣugbọn omi tí à ń mu kò dára, bẹ́ẹ̀ ni ilẹ̀ náà sì jẹ́ aṣálẹ̀.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 2

Wo Àwọn Ọba Keji 2:19 ni o tọ