Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 17:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá pàṣẹ, ó ní, “Ẹ dá ọ̀kan ninu àwọn alufaa tí a kó lẹ́rú pada sí Samaria, kí ó lè kọ́ àwọn eniyan náà ní òfin Ọlọrun ilẹ̀ náà.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17

Wo Àwọn Ọba Keji 17:27 ni o tọ