Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 17:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá lọ ròyìn fún ọba Asiria pé àwọn eniyan tí ó kó lọ sí ilẹ̀ Samaria kò mọ òfin Ọlọrun ilẹ̀ náà, nítorí náà ni Ọlọrun ṣe rán kinniun tí ó ń pa wọ́n.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17

Wo Àwọn Ọba Keji 17:26 ni o tọ