Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 17:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ọ̀kan ninu àwọn alufaa tí wọ́n kó wá láti Samaria pada lọ, ó sì ń gbé Bẹtẹli, níbẹ̀ ni ó ti ń kọ́ àwọn eniyan náà bí wọn yóo ṣe máa sin OLUWA.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17

Wo Àwọn Ọba Keji 17:28 ni o tọ