Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 11:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Joaṣi ọmọ Ahasaya nìkan ni kò pa nítorí pé Jehoṣeba ọmọbinrin Joramu ọba, arabinrin Ahasaya, gbé e sá lọ; ó sì fi òun ati alágbàtọ́ rẹ̀ pamọ́ sí yàrá kan ninu ilé OLUWA, kí Atalaya má baà pa á. Ó gbé e pamọ́ fún Atalaya, Atalaya kò sì rí i pa.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 11

Wo Àwọn Ọba Keji 11:2 ni o tọ