Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 11:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní kété tí Atalaya, ìyá ọba Ahasaya gbọ́ nípa ikú ọmọ rẹ̀, ó pa gbogbo ìdílé ọba run.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 11

Wo Àwọn Ọba Keji 11:1 ni o tọ