Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 9:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jotamu gbọ́, ó gun orí òkè Gerisimu lọ, ó bẹ̀rẹ̀ sí kígbe pé, “Ẹ fi etí sílẹ̀, ẹ̀yin ọkunrin Ṣekemu, kí Ọlọrun lè gbọ́ tiyín.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9

Wo Àwọn Adájọ́ 9:7 ni o tọ