Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 9:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò kan, àwọn igi oko kó ara wọn jọ pé wọ́n fẹ́ ọba, wọ́n lọ sọ́dọ̀ igi Olifi, wọ́n wí fún un pé kí ó máa jọba lórí wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9

Wo Àwọn Adájọ́ 9:8 ni o tọ