Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 8:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ni Ọlọrun fi Orebu ati Seebu, àwọn ọmọ ọba Midiani mejeeji lé lọ́wọ́. Kí ni ohun tí mo ṣe lẹ́gbẹ̀ẹ́ èyí tí ẹ̀yin ṣe?” Nígbà tí wọ́n gbọ́ bí ó ṣe dá wọn lóhùn, inú wọ́n yọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 8

Wo Àwọn Adájọ́ 8:3 ni o tọ