Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 8:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Gideoni bá lọ sí odò Jọdani, ó sì kọjá odò náà sí òdìkejì rẹ̀, òun ati àwọn ọọdunrun (300) ọkunrin tí wọ́n tẹ̀lé e. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti rẹ̀ wọ́n, sibẹsibẹ wọ́n ń lé àwọn ará Midiani lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 8

Wo Àwọn Adájọ́ 8:4 ni o tọ