Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 20:35 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá ṣẹgun àwọn ará Bẹnjamini fún àwọn ọmọ Israẹli. Àwọn ọmọ Israẹli pa ọ̀kẹ́ kan ati ẹgbẹẹdọgbọn ó lé ọgọrun-un (25,100) eniyan ninu àwọn ará Bẹnjamini lọ́jọ́ náà. Gbogbo àwọn tí wọ́n pa jẹ́ jagunjagun tí wọn ń lo idà.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:35 ni o tọ