Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 19:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Èdè-àìyedè kan bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn mejeeji, obinrin yìí bá kúrò lọ́dọ̀ ọkunrin náà, ó lọ sí ilé baba rẹ̀ ní Bẹtilẹhẹmu, ó sì ń gbé ibẹ̀ fún nǹkan bí oṣù mẹrin.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 19

Wo Àwọn Adájọ́ 19:2 ni o tọ