Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 19:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò tí kò sí ọba ní Israẹli, ọmọ Lefi kan ń gbé apá ibìkan tí ó jìnnà ní agbègbè olókè ti Efuraimu. Ọmọ Lefi yìí ní obinrin kan tí ó jẹ́ ará Bẹtilẹhẹmu ni ilẹ̀ Juda.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 19

Wo Àwọn Adájọ́ 19:1 ni o tọ