Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 19:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ọkọ rẹ̀ dìde, ó lọ bẹ̀ ẹ́ pé kí ó pada. Ọkunrin yìí mú iranṣẹ kan ati kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ bíi meji lọ́wọ́. Nígbà tí ó dé ilé baba obinrin rẹ̀ yìí, tí baba iyawo rẹ̀ rí i, ó lọ pàdé rẹ̀ tayọ̀tayọ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 19

Wo Àwọn Adájọ́ 19:3 ni o tọ