Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 16:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Samsoni dá a lóhùn pé, “Bí wọ́n bá fi awọ tí wọ́n fi ń ṣe ọrun, tí kò tíì gbẹ meje dè mí, yóo rẹ̀ mí, n óo sì dàbí àwọn ọkunrin yòókù.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16

Wo Àwọn Adájọ́ 16:7 ni o tọ