Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 16:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọba Filistini bá kó awọ tí wọ́n fi ń ṣe ọrun, titun, meje, tí kò tíì gbẹ, fún Delila, ó sì fi so Samsoni.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16

Wo Àwọn Adájọ́ 16:8 ni o tọ