Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 16:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Delila mú kí Samsoni sùn lórí ẹsẹ̀ rẹ̀, ó bá pe ọkunrin kan pé kí ó fá ìdì irun mejeeje tí ó wà ní orí Samsoni. Ó bá bẹ̀rẹ̀ sí jẹ ẹ́ níyà, agbára rẹ̀ sì fi í sílẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16

Wo Àwọn Adájọ́ 16:19 ni o tọ