Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 16:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wí fún un pé, “Samsoni! Àwọn ará Filistia ti dé.” Samsoni bá jí láti ojú oorun, ó ní, “N óo lọ bí mo ti máa ń ṣe tẹ́lẹ̀, n óo sì gba ara mi lọ́wọ́ wọn.” Kò mọ̀ pé OLUWA ti fi òun sílẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16

Wo Àwọn Adájọ́ 16:20 ni o tọ