Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 14:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Baba ati ìyá rẹ̀ dá a lóhùn pé, “Ṣé kò sí obinrin mọ́ ninu gbogbo àwọn ìbátan rẹ tabi láàrin gbogbo àwọn eniyan wa ni o fi níláti lọ fẹ́ aya láàrin àwọn ará Filistia aláìkọlà ni?”Samsoni bá bẹ baba rẹ̀, ó ní, “Ẹ ṣá fẹ́ ẹ fún mi nítorí ó wù mí pupọ.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 14

Wo Àwọn Adájọ́ 14:3 ni o tọ