Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 14:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó pada wálé wá sọ fún baba ati ìyá rẹ̀, ó ní, “Mo rí ọ̀kan ninu àwọn ọmọbinrin ará Filistia ní Timna, ó wù mí, ẹ jọ̀wọ́, ẹ fẹ́ ẹ fún mi.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 14

Wo Àwọn Adájọ́ 14:2 ni o tọ