Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 14:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn baba ati ìyá rẹ̀ kò mọ̀ pé ọ̀rọ̀ náà ní ọwọ́ OLUWA ninu, nítorí pé OLUWA ti ń wá ọ̀nà láti mú àwọn ará Filistia nítorí pé, àwọn ni wọ́n ń mú àwọn ọmọ Israẹli sìn ní àkókò yìí.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 14

Wo Àwọn Adájọ́ 14:4 ni o tọ