Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 9:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí àwọn ọ̀tá bá kó wọn lẹ́rú, tí wọn ń kó wọn lọ, n óo pàṣẹ pé kí àwọn ọ̀tá pa wọ́n. N óo dójúlé wọn láti ṣe wọ́n ní ibi, n kò ní ṣe wọ́n ní rere.”

Ka pipe ipin Amosi 9

Wo Amosi 9:4 ni o tọ