OLUWA, Ọlọrun àwọn ọmọ ogun,òun ló fọwọ́ kan ilẹ̀,tí ilẹ̀ sì yọ́,tí gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀ ń ṣọ̀fọ̀,tí gbogbo nǹkan ru sókè bí odò Naili,tí ó sì lọ sílẹ̀ bí odò Naili ti Ijipti;