Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n bá sápamọ́ sórí òkè Kamẹli, n óo wá wọn kàn níbẹ̀; n óo sì mú wọn. Bí wọ́n bá sá kúrò níwájú mi, tí wọ́n sápamọ́ sí ìsàlẹ̀ òkun, n óo pàṣẹ fún ejò níbẹ̀, yóo sì bù wọ́n jẹ.

Ka pipe ipin Amosi 9

Wo Amosi 9:3 ni o tọ