Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 60:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Oòrùn rẹ kò ní wọ̀ mọ́,bẹ́ẹ̀ ni òṣùpá rẹ kò ní wọ òkùnkùn.Nítorí OLUWA ni yóo jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ayérayé fún ọ,ọjọ́ ọ̀fọ̀ rẹ yóo sì dópin.

Ka pipe ipin Aisaya 60

Wo Aisaya 60:20 ni o tọ