Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 60:19 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kì í ṣe oòrùn ni yóo máa tan ìmọ́lẹ̀ fún ọ mọ́ ní ọ̀sán,bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe òṣùpá ni yóo máa tan ìmọ́lẹ̀ fún ọ mọ́ ní òru:OLUWA ni yóo máa jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ayérayé fún ọ,Ọlọrun rẹ yóo sì jẹ́ ògo rẹ.

Ka pipe ipin Aisaya 60

Wo Aisaya 60:19 ni o tọ