Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 60:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò tún ní sí ìró ìdàrúdàpọ̀ ní ilẹ̀ rẹ mọ́,kò sì ní sí ìdágìrì ati ìparun ní ibodè rẹ,o óo máa pe odi rẹ ní ìgbàlà,o óo sì máa pe ẹnubodè rẹ ní ìyìn.

Ka pipe ipin Aisaya 60

Wo Aisaya 60:18 ni o tọ