Wọ̀bìà ni wọ́n, alájẹkì,wọn kì í yó.Àwọn olùdarí wọn pàápàá kò mọ nǹkankan.Gbogbo wọn ti tẹ̀ sí ọ̀nà ara wọn,olukuluku wọn ń wá èrè fún ara rẹ̀.