Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 56:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Afọ́jú ni àwọn aṣọ́de Israẹligbogbo wọn kò mọ nǹkankan.Ajá tí ó yadi ni wọ́n,wọn kò lè gbó;oorun ni wọ́n fẹ́ràn.Wọn á dùbúlẹ̀, wọn á máa lá àlá.

Ka pipe ipin Aisaya 56

Wo Aisaya 56:10 ni o tọ