Òwìwí yóo pa ìtẹ́ sibẹ, tí yóo máa yé sí.Yóo pamọ, yóo ràdọ̀ bo àwọn ọmọ rẹ̀,yóo sì máa tọ́jú wọn níbẹ̀.Àwọn àṣá yóo péjọ sibẹ,olukuluku wọn, pẹlu ekeji rẹ̀.