Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 34:14 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn ẹranko ìgbẹ́ ati ìkookò yóo jọ máa gbé ibẹ̀,àwọn ewúrẹ́ igbó yóo máa ké pe ara wọn.Iwin yóo rí ibi máa gbé,yóo sì rí ààyè máa sinmi níbẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 34

Wo Aisaya 34:14 ni o tọ